On at about 12:15:20 PM, Konstant - Morenikeji (Official Video) was updated.
Mp3 & Mp4 Download » Konstant - Morenikeji Video; Fresh from our hub, We present to you trendy love gbedu from way back by Konstant; this trendy love audio/song is titled 'Morenikeji'.
in about 7 years, DWM's current act Ayanfe dropped a freestyle imitating this beautiful song titled 'Morenikeji' by Konstant; Morenikeji was also featured in a popular Yoruba movie/file titled 'Ayo Mi' [Bukunmi Oluwasina Ayo Mi 'Soundtrack']
This is a must cop to include in your playlist.
ENJOY!!!
QUOTABLE LYRICS!: Konstant - Morenikeji
Bojo Ife Ku Ma Lo Eh, Bi Ina Ife Jo Mi Mio Fo Ya…
Ife Re Ni Okan Mi, Otutu Bi Omi Amo, You Feel My Heart With That Love Life And Emotions… ‘Moti Renikeji Mi, Eni Bi Okan Mi, Mo Fe Rin Ajo Ife; Je N Fa Eh Lowo Dani, Ki Oko Ife Gbe Wa Lo, Girl I Cannot Leave Without You! Ololufe Mi.’
Mio Ni Fi Gba Kan Bo Kan Ninu, Mio Ni Fi Eh Si Ile Mo Ife Mi, Mi O Ni Gbagbe Re Kokoro Kun Ko Mo Osa O. Ekuro Sha Ni Ala Ba Ku Ewa O!
Mo ti rìn jìnà, mo ti rábúké òkéré, Olólùfé mi màá ké e, Màá tún gè é, Nígbà òjò Nígbà èrùn, okò ìfé wa ò ní dànù, Ìpìnlè ìfé wa ló rí òdodo ló wà
You are my life, you are my wife, In all situation girl I cannot deny, Mi ò ní figbá kan bòkan nínú, Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi
Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o, Èkùró shá ni alábákú èwà., Mi ò ní figbá kan bòkan nínú
Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi, Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o, Èkùró shá ni alábákú èwà.
I'm sure you will linger linger on, Down deep my soul, I hear your whispers in my dreams, Oh yes I know, Across the ocean, even across the sea, You will always be the one I love.
I'm sure you will linger linger on, Down deep my soul, I hear your whispers in my dreams, Oh yes I know, Across the ocean, even across the sea,
You will always be the one I love., Ìwo olólùfé, Màá ri pé mo tójú e, Bébí Ará kò e, Mi ò ní fi é sílè, Lágbára oníbú ore, a màá pé lórí ilè, To show you love and care eh eh eh eh.
Mi ò ní figbá kan bòkan nínú
Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi
Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o
Èkùró shá ni alábákú èwà.
Mi ò ní figbá kan bòkan nínú
Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi
Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o
Èkùró shá ni alábákú èwà.
You gave me everything, I ever wanted,, Love from heaven right on me descend, When I was still alone, my life was not so sure, How can I make a better one?
Girl you know there's this feelings I can't define, Feeling high feeling high oh oh uh oh
Girl you know there's this feelings I can't define, Feeling high feeling high oh oh uh oh
Ìfé I love you more than imagination, imagination, Ìfé I love you more than imagination, imagination
Oh ah, oh ah hu ah hu, Kò n se tìgbéraga mo mòn,
èkùró lalábákú èwà temi, èkùró shá ni alábákú èwà
Kò n se tìgbéraga mo mòn,
èkùró lalábákú èwà temi, èkùró shá ni alábákú èwà
Ojú kan Làdá mi ni o,
èkùró lalábákú èwà temi, èkùró shá ni alábákú èwà
hit the jump, watch video! and Download 'Konstant Morenikeji Mp4 Mp3' Below!
DOWNLOAD!: Konstant - Morenikeji MP3
Find DJ More Music NG to be useful? Click here to give us five stars rating!
META TAGS