- Artist: Konstant
- Album: Morenikeji
- Released: 2015 Ⓡ
Fresh from our hub, We present to you a trendy love song from way back by Konstant; this trendy love song is titled 'Morenikeji.'
Morenikeji's song by singer; Konstant also known as constant — In about 7 years, DWM's current act Ayanfe dropped a freestyle imitating this beautiful song titled 'Morenikeji' by Konstant.
Morenikeji was also featured in a popular Yoruba movie/file titled 'Ayo Mi' [Bukunmi Oluwasina Ayo Mi 'Soundtrack']. Thos lovely track by Konstant—Motirenikeji mi by Konstant.
This is a must cop to include in your playlist.
Bojo Ife Ku Ma Lo Eh, Bi Ina Ife Jo Mi Mio Fo Ye; Ife Re Ni Okan Mi, Otutu Bi Omi Amo, You Feel My Heart With That Love Life And Emotions… ‘Moti Renikeji Mi, Eni Bi Okan Mi, Mo Fe Rin Ajo Ife; Je N Fa Eh Lowo Dani, Ki Oko Ife Gbe Wa Lo, Girl I Cannot Leave Without You! Ololufe Mi.’
Konstant - Morenikeji — Mio Ni Fi Gba Kan Bo Kan Ninu, Mio Ni Fi Eh Si Ile Mo Ife Mi, Mi O Ni Gbagbe Re Kokoro Kun Ko Mo Osa O. Ekuro Sha Ni Ala Ba Ku Ewa O! Mo ti rìn jìnà, mo ti rábúké òkéré, Olólùfé mi màá ké e, Màá tún gè é, Nígbà òjò Nígbà èrùn, okò ìfé wa ò ní dànù, Ìpìnlè ìfé wa ló rí òdodo ló wà; You are my life, you are my wife, In all situation girl I cannot deny, Mi ò ní figbá kan bòkan nínú, Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi.
Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o, Èkùró shá ni alábákú èwà., Mi ò ní figbá kan bòkan nínú Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi, Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o, Èkùró shá ni alábákú èwà.
I'm sure you will linger linger on, Down deep my soul, I hear your whispers in my dreams, Oh yes I know, Across the ocean, even across the sea, You will always be the one I love. I'm sure you will linger linger on, Down deep my soul, I hear your whispers in my dreams, Oh yes I know, Across the ocean, even across the sea, you will always be the one I love., Ìwo olólùfé, Màá ri pé mo tójú e, Bébí Ará kò e, Mi ò ní fi é sílè, Lágbára oníbú ore, a màá pé lórí ilè, To show you love and care eh eh eh eh.
STICK YOUR CONTENT HERE (Daily ADs)
Mi ò ní figbá kan bòkan nínú Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o Èkùró shá ni alábákú èwà. Mi ò ní figbá kan bòkan nínú Mi ò ní fi é sílè món ìfé mi Mi ò ní gbàgbé re bo bá rókun bó ròsà o Èkùró shá ni alábákú èwà.
You gave me everything, I ever wanted,, Love from heaven right on me descend, When I was still alone, my life was not so sure, How can I make a better one?
Girl you know there's this feelings I can't define, Feeling high feeling high oh oh uh oh x2
Ìfé I love you more than imagination, imagination, Ìfé I love you more than imagination, imagination Oh ah, oh ah hu ah hu, Kò n se tìgbéraga mo mòn, èkùró lalábákú èwà temi, èkùró shá ni alábákú èwà; Kò n se tìgbéraga mo mòn, èkùró lalábákú èwà temi, èkùró shá ni alábákú èwà Ojú kan Làdá mi ni o, èkùró lalábákú èwà temi, èkùró shá ni alábákú èwà
hit the jump and Download 'Konstant Morenikeji Mp3' Below!
Konstant - Morenikeji instant indexed bitrate: 160kbps. Listen to this SONG! [5.7MB]: Konstant - Morenikeji MP3 Download – stream high-quality music audio. Check-in.

Tife - 1 year ago
Tife - 1 year ago
Wura - 12 months ago
Wura - 12 months ago
Anita - 11 months ago